Wá níló: Áwón ọ́pá ísẹ́, fóómú óólẹ́, Bébá kílìpú, própẹ́lá, Ókún roba, bébá, sísọ́sí, asáámí,
1
Áfíkún áwón ígí ísẹ́ ọ́wọ́ átí ásópọ pẹ́lú fóómú álálẹ́pọ́ - sátunsè gìgún wón, gígún ábí kúkúrú.
2
Sò própẹ́lá sí ópín ọpá kán.
3
Tẹ́ẹ́ bébá kìlìpú, kí ó sómọ́ ọpá ìsẹ́ ọwọ ìpárí mìrán, pẹ́lú fóómú óólẹ́
4
Só ókún rọbá larìn própẹ́lá átì bébá kílìpú
5
Sẹ́dá fúsílèjí! Yá áwórán apẹ́rẹ́ éyíkéyí pẹ́lú ásáámí sórí ìwé, kí ósí gé jádé.
6
Gé fóómú óólẹ́ sí ídájí, kíó só áwón íyẹ́ sì ọpá ìsẹ́.
7
Fẹ́ áfẹ́fẹ́ sínú própẹ́lá látí dánwó, Íwọ yóó nìló áwón ákókó 50 tábí dìẹ́ síí látí jẹ́ kíó fó!
8
Sádánwó pẹ́lú áwón ápẹ́rẹ́ írìsì ápá
9
Wá ágbégbé áábó ófúrúfú kíó sè yí própẹ́lá bi ọ́wọ́ áágó. Tú própẹ́lá, lẹ́hínná sé ífílọlẹ́ fúsílèjí!
10
Explore more Jumprope
Want to create? It’s fast, easy, free & open to anyone.
Learn more.
More than 50,000 step-by-step guides to learn how to do anything.